29 captures
16 Sep 2012 - 08 Dec 2024
Jan FEB Mar
05
2012 2013 2014
success
fail

About this capture

COLLECTED BY

Organization: Internet Archive

The Internet Archive discovers and captures web pages through many different web crawls. At any given time several distinct crawls are running, some for months, and some every day or longer. View the web archive through the Wayback Machine.

Collection: Wide Crawl Started January 2013

Wide crawls of the Internet conducted by Internet Archive. Access to content is restricted. Please visit the Wayback Machine to explore archived web sites.
TIMESTAMPS

The Wayback Machine - http://web.archive.org/web/20130205070555/http://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%BA%B8%CC%80s%C3%ACn-%C3%ACn_H%C3%ADnd%C3%B9
 




̀sìn-ìn Híndù

 

Lát'ẃ Wikipedia, ìwé ìm̀ ̀f́
 

L sí: at́ka, àwárí  

Esin Hindu ni èsìn ti ó lójó lórí jùlo, tó si lààmi-laaka jùlo nínú gbogbo àwon èsin. Ònà láti se èkúnréré àlàyé ìdàgbàsóké èsìn Hindu ta kókó púpò nítorí pé a kòlè so pàtó eni tó se agbáterù ìdásílè rè sùgbón inú àwon ìse èsìn èyà Aryan ti wón si lo si orílè-èdè India láti ààrin gbùngbùn Asia ló ti sè wá ní bi i i egbèrún odún méta séyìn. Àwon èyà Aryan gbógun ti àwon aráa Arapánì ti wón gbé ni orilè èdè India tòní ni bíi odún 500BC Séyìn. Àsèyín wá, àsèyìn bò, nípa ìfaramolé pèlú ìgbàgbó èsìn keji, àwon èyà méjéèjì se àgbékalè ìlànàn ìgbàgbó èsìn kan ná-àn to dálóríi ìgbàgbò pé èyà Aryan ni ju olórun kan lo àti ìwà ni mímó ìsèso, èyà Hárápáni. Láìpé, àwùjo to kún fún èyà Aryàn se àgbédìde ìlànà ti kò fààyè gba èyà mìíràn wón si se ìpínrò àwùjo won gégé bi isé owóo won se lóóòrìn sí.

Èsin Hindu dá lóri pé èmi ènìyàn àti èmi, eranko to ti kú sí n padà wá sáyé láti máa gbé láimo iye ìgbà àti ni orísiirísii ònàn. Ìgbàgbó pé èmi n lo sókè sódò lónà ta ò le so ni pàtó nipa ìwà èyi tí àwon Hindu yàn je yo nínú àwon àgbékalè isesi won. Ìlànàn ti kò fi àyè gba irúfé èyà miiràn yè, a kò sì gbo rárá pé èya kàn yónú si èyà kejì nítorí pé enikòòkan won ló n du ipò láwùjo ti a gbé bii. A fi elòmíràn si àwùjo tó ga jùlo nítorí pé ó ti hùwà omolúàbí séyìn, ní gbà ti a bi elòmiràn si àwùjo tó tòsi nítorí pé ó ti siwà hù séyìn.

Lónìí, elésin-ín Hindu le gbàgbó pé olórun jù òkan lo, òmíràn lè gbà pé òkan nì, a tún lerí èyi ti ó gbàgbó pé òkan ni olórun àti gbogbo àgba nlá ayé, béè a si tún ri èyi tó gbà pé kò si olorún rárá. Èyi mú ki ó sòro láti jiròrò lórii ìgbàgbó èsìn-in Hindu ni pàtó niwòn ìgbà tó jé wí pé orísiirísii ni òye tó wà nípa èsin Hindu. Nítorí ná-àn à gbodò má ménu ba àwon kókó wònyí.

Pàtàkì, si èsin, Hindu ni ètò ayé àtúnwá, èto èyà ti kò fi àyè gba òmiràn, tó dàpò pèlú ìsèlè tó lààmi laaka, wiwá ìwà omolúàbi àti bibó lówó sikún ayé àtúnwá lálàáfíà.

Lára àwon ònàn èsìn Hindù si igbàlà ni ònàn ìrúbo, mímo àwon ìsèlè tòóótó, ònàn ìfara eni ji, ìfara eni ji fún olórun èyi tó yàn láti tèlé. Bi àwon elésìn yii bá tèlé àwon ààlà àwon ònàn yi, ìgbàlà yóò jé tiwon.


Edit-find-replace.svg Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.


[àtúnṣe] Itokasi


J́ kíkójáde láti "http://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=̀sìn-ìn_Híndù&oldid=428573" 

̀ka: 
Ìehíndù
̀ka bíbòḿl̀: 
̀kúnŕŕ
 

Ètò ìt́śnà

 

Àwn iriń àdáni



 fi orúk síl̀
Ìwlé
 



Àwn orúkàyè



Àykà

̀r̀
 


Àwn oriiríi








Àwn ìwò



Àwòkà

Àtúne

Wo ìtàn
 


Àwn ìgbée












At́ka




Ojúewé Àḱḱ

Ìpele Àykà

Àykà pàtàkì

Ì̀l̀ ĺẃĺẃ

Ojúewé àrìnàkò
 



Ìkópa




Àwn àtúne tuntun

Èbúté àwùj

Ab́ igi

Ìrànĺẃ

Ìf̀r̀ránś

Se ̀bùn owó
 



Àpótí irin




Ìjáp̀ ḿ ojúewé yí

Àtúne tó báramu

Àwn ojúewé pàtàkì

Àt̀jáde tóeét̀síìwé

Ìjáp̀ tíkòníyípadà

̀r̀̀kúnŕŕ ojúewé

Cite this page
 



Àwn èdè míràn




Afrikaans

Alemannisch

Aragonés

العربية

مصرى



Asturianu

Azərbaycanca

Boarisch

Žemaitėška

Bikol Central

Беларуская

Беларуская (тарашкевіца)

Български



Bahasa Banjar





িি ি

Brezhoneg

Bosanski

Català

Cebuano

کوردی

Corsu

Česky

Cymraeg

Dansk

Deutsch

ދިވެހިބަސް

Ελληνικά

English

Esperanto

Español

Eesti

Euskara

Estremeñu

فارسی

Suomi

Võro

Føroyskt

Français

Arpetan

Furlan

Frysk

Gaeilge



Gàidhlig

Galego



עברית

ि

Fiji Hindi

Hrvatski

Kreyòl ayisyen

Magyar

Հայերեն

Interlingua

Bahasa Indonesia

Interlingue

Ilokano

Ido

Íslenska

Italiano



Basa Jawa



Қазақша







Kurdî

Kernowek

Latina

Ladino

Lëtzebuergesch

Лезги

Limburgs

Lietuvių

Latviešu

Basa Banyumasan

Македонски



Монгол



Bahasa Melayu

Malti

Mirandés



Plattdüütsch



 

Nederlands

Norsk (nynorsk)

Norsk (bokmål)

Occitan

ି



Papiamentu

Norfuk / Pitkern

Polski

Piemontèis

پنجابی

پښتو

Português

Runa Simi

Română

Русский

Русиньскый



Саха тыла

Scots

Sámegiella

Srpskohrvatski / српскохрватски

Simple English

Slovenčina

Slovenščina

Shqip

Српски / srpski

Basa Sunda

Svenska

Kiswahili

ி



Тоҷикӣ



Türkmençe

Tagalog

Türkçe

Українська

اردو

Tiếng Vit

Walon

Winaray

ייִדיש



Bân-lâm-gú


 





Àtune ojúewé yi gb̀yìn wáyé ni ago 12:10, j́dún 5 Où Kínní 2013.

Gbogbo ìk wà láb́ Creative Commons Attribution/Share-Alike License; ó e é e kí àwn ̀r̀ àdéhùn míràn tún wà.  wo Àwn ̀r̀ Àdéhùn Ìlò fún ̀kúnŕŕ.
Wikipedia® ni àmììtajà fífilórúksíl̀ Wikimedia Foundation, Inc., àgbáj èrè ḱ.
Ìbápàdé wa
 


Ètò àbò

Nípa Wikipedia

Ikìl̀

Mobile view
 


Wikimedia Foundation
Powered by MediaWiki